Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 9:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun ní, “Ṣebí bí ẹ ti jẹ́ sí mi ni àwọn ará Etiopia náà jẹ́, ẹ̀yin ọmọ Israẹli? Àbí kì í ṣe bí mo ti mú àwọn ará Filistia jáde láti ìlú Kafitori, tí mo mú àwọn Siria jáde láti ìlú Kiri, ni mo mú ẹ̀yin náà jáde láti Ijipti.

Ka pipe ipin Amosi 9

Wo Amosi 9:7 ni o tọ