Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 9:14 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo dá ire Israẹli, àwọn eniyan mi, pada,wọn yóo tún àwọn ìlú tí wọ́n ti wó kọ́,wọn yóo sì máa gbé inú wọn.Wọn yóo gbin àjàrà,wọn yóo sì mu ọtí waini rẹ̀.Wọn yóo ṣe ọgbà,wọn yóo sì jẹ èso rẹ̀.

Ka pipe ipin Amosi 9

Wo Amosi 9:14 ni o tọ