Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 8:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀ ń sọ pé: “Nígbà wo ni ìsinmi oṣù titun yóo parí, kí á lè rí ààyè ta ọkà wa? Nígbà wo sì ni ọjọ́ ìsinmi yóo kọjá, kí á lè rí ààyè ta alikama, kí á lè gbówó lé ọjà wa, kí á sì lo òṣùnwọ̀n èké, láti rẹ́ àwọn oníbàárà wa jẹ;

Ka pipe ipin Amosi 8

Wo Amosi 8:5 ni o tọ