Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 8:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tó bá yá, orin inú tẹmpili yóo di ẹkún, òkú yóo sùn lọ kítikìti níbi gbogbo, a óo kó wọn dà síta ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Amosi 8

Wo Amosi 8:3 ni o tọ