Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 8:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo máa lọ káàkiri láti òkun dé òkun, láti ìhà àríwá sí ìhà ìlà oòrùn. Wọn yóo máa sá sókè sódò láti wá ọ̀rọ̀ Ọlọrun, ṣugbọn wọn kò ní rí i.

Ka pipe ipin Amosi 8

Wo Amosi 8:12 ni o tọ