Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 7:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Amasaya sọ fún Amosi pé, “Ó tó gẹ́ẹ́, ìwọ aríran, pada lọ sí ilẹ̀ Juda, máa lọ sọ àsọtẹ́lẹ̀ níbẹ̀, kí wọ́n sì máa fún ọ ní oúnjẹ.

Ka pipe ipin Amosi 7

Wo Amosi 7:12 ni o tọ