Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 7:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Amasaya, alufaa Bẹtẹli, ranṣẹ sí Jeroboamu, ọba Israẹli pé: “Amosi ń dìtẹ̀ mọ́ ọ láàrin àwọn ọmọ Israẹli, ọ̀rọ̀ rẹ̀ yóo sì ba gbogbo ilẹ̀ yìí jẹ́.

Ka pipe ipin Amosi 7

Wo Amosi 7:10 ni o tọ