Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 6:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, àwọn ni wọn yóo kọ́kọ́ lọ sí ìgbèkùn, gbogbo àsè ati ayẹyẹ àwọn tí wọn ń nà kalẹ̀ sórí ibùsùn yóo dópin.

Ka pipe ipin Amosi 6

Wo Amosi 6:7 ni o tọ