Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ lọ wo ìlú Kane; ẹ ti ibẹ̀ lọ sí Hamati, ìlú ńlá nì, lẹ́yìn náà ẹ lọ sí ìlú Gati, ní ilẹ̀ àwọn ará Filistia. Ṣé wọ́n sàn ju àwọn orílẹ̀-èdè yín lọ ni? Tabi agbègbè wọn tóbi ju tiyín lọ?

Ka pipe ipin Amosi 6

Wo Amosi 6:2 ni o tọ