Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 5:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń retí ọjọ́ OLUWA, ẹ gbé! Kí ni ẹ fẹ́ fi ọjọ́ OLUWA ṣe? Ọjọ́ òkùnkùn ni, kì í ṣe ọjọ́ ìmọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Amosi 5

Wo Amosi 5:18 ni o tọ