Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 5:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kórìíra ibi, kí ẹ sì fẹ́ ire, ẹ jẹ́ kí ìdájọ́ òdodo gbilẹ̀ lẹ́nu ibodè yín; bóyá OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun yóo ṣàánú fún àwọn ọmọ ilé Josẹfu yòókù.

Ka pipe ipin Amosi 5

Wo Amosi 5:15 ni o tọ