Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 4:4 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Ẹ wá sí Bẹtẹli, kí ẹ wá máa dẹ́ṣẹ̀ níbẹ̀, kí ẹ sì wá fi ẹ̀ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀ ní Giligali; ẹ máa mú ẹbọ yín wá ní àràárọ̀, ati ìdámẹ́wàá yín ní ọjọ́ kẹta kẹta.

Ka pipe ipin Amosi 4

Wo Amosi 4:4 ni o tọ