Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 4:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Mo fi irú àwọn àjàkálẹ̀ àrùn tí ó jà ní Ijipti ba yín jà, mo fi idà pa àwọn ọdọmọkunrin yín lójú ogun; mo kó ẹṣin yín lọ, mo mú kí òórùn àwọn tí wọ́n kú ninu àgọ́ yín wọ̀ yín nímú; sibẹsibẹ ẹ kò pada sọ́dọ̀ mi.

Ka pipe ipin Amosi 4

Wo Amosi 4:10 ni o tọ