Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 2:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, n óo sọ iná sí Moabu, yóo sì jó àwọn ibi ààbò Kerioti ní àjórun. Ninu ariwo ogun ati ti fèrè ni Moabu yóo parun sí,

Ka pipe ipin Amosi 2

Wo Amosi 2:2 ni o tọ