Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo yan àwọn kan ninu àwọn ọmọ yín ní wolii mi, mo sì yan àwọn mìíràn ninu wọn ní Nasiri. Àbí bẹ́ẹ̀ kọ́, ẹ̀yin ọmọ Israẹli? Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Amosi 2

Wo Amosi 2:11 ni o tọ