Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Àwọn ará Damasku ń dẹ́ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀, dájúdájú, n óo jẹ wọ́n níyà. Wọ́n mú ohun èlò ìpakà onírin ṣómúṣómú, wọ́n fi pa àwọn ará Gileadi ní ìpa ìkà.

Ka pipe ipin Amosi 1

Wo Amosi 1:3 ni o tọ