Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní: “Àwọn ará Amoni ń dẹ́ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀, dájúdájú, n óo jẹ wọ́n níyà; wọ́n fi ìwà wọ̀bìà bẹ́ inú àwọn aboyún ilẹ̀ Gileadi, láti gba ilẹ̀ kún ilẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Amosi 1

Wo Amosi 1:13 ni o tọ