Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 1:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìran tí Amosi, ọ̀kan ninu àwọn darandaran Tekoa, rí nípa Israẹli nìyí, nígbà ayé Usaya, ọba Juda, ati Jeroboamu, ọmọ Jehoaṣi, ọba Israẹli, ní ọdún meji ṣáájú ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ṣẹlẹ̀ tí ilẹ̀ fi mì jìgìjìgì.

Ka pipe ipin Amosi 1

Wo Amosi 1:1 ni o tọ