Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 9:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń já nǹkan gbà lọ́tùn-ún, wọ́n ń jẹ ẹ́,sibẹ ebi ń pa wọ́n.Wọ́n ń jẹ àjẹrun lósì,sibẹ wọn kò yó,àwọn eniyan sì ń pa ara wọn jẹ.

Ka pipe ipin Aisaya 9

Wo Aisaya 9:20 ni o tọ