Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 8:7 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí náà, ẹ wò ó, OLUWA yóo gbé ọba Asiria ati gbogbo ògo rẹ̀ dìde wá bá wọn, yóo sì bò wọ́n mọ́lẹ̀ bí omi odò Yufurate, tí ó kún àkúnya, tí ó sì kọjá bèbè rẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 8

Wo Aisaya 8:7 ni o tọ