Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 7:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn yóo sì rọ́ wá sí ààrin àwọn àfonífojì, ati gbogbo kọ̀rọ̀ kọ̀rọ̀ ní ààrin àpáta, ati ara gbogbo igi ẹlẹ́gùn-ún ati gbogbo pápá.

Ka pipe ipin Aisaya 7

Wo Aisaya 7:19 ni o tọ