Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 66:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó! OLUWA ń bọ̀ ninu iná,kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ yóo dàbí ìjì,láti fi ìrúnú san ẹ̀san,yóo sì fi ahọ́n iná báni wí.

Ka pipe ipin Aisaya 66

Wo Aisaya 66:15 ni o tọ