Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 65:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí eniyan tíí wòye pé ọtí wà lára ìdì èso àjàrà,tí wọn sìí sọ pé, ‘Ẹ má bà á jẹ́,nítorí ohun rere wà ninu rẹ̀,’bẹ́ẹ̀ ni n óo ṣe nítorí iranṣẹ mi,n kò ní pa gbogbo wọn run.

Ka pipe ipin Aisaya 65

Wo Aisaya 65:8 ni o tọ