tí wọn ń ṣe ohun tí yóo mú mi bínú,níṣojú mi, nígbà gbogbo.Wọ́n ń rúbọ ninu oríṣìíríṣìí ọgbà,wọ́n ń sun turari lórí bíríkì.