Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 65:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ṣetán láti mú kí àwọn tí kò bèèrè mi máa wá mi,ati láti fi ara mi han àwọn tí kò wá mi.Mo sọ fún orílẹ̀-èdè tí kì í gbadura ní orúkọ mi pé,“Èmi nìyí, èmi nìyí.”

Ka pipe ipin Aisaya 65

Wo Aisaya 65:1 ni o tọ