Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 64:11-12 BIBELI MIMỌ (BM)

11. Wọ́n ti dáná sun ilé mímọ́ wa tí ó lẹ́wà,níbi tí àwọn baba wa ti yìn ọ́,gbogbo ibi dáradára tí a ní, ló ti di ahoro.

12. OLUWA, ṣé o kò ní ṣe nǹkankan sí ọ̀rọ̀ yìí ni?Ṣé o óo dákẹ́, o óo máa fìyà jẹ wá ni?

Ka pipe ipin Aisaya 64