Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 63:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ó ranti ìgbà àtijọ́,ní àkókò Mose, iranṣẹ rẹ̀.Wọ́n bèèrè pé,ẹni tí ó kó wọn la òkun já dà?Olùṣọ́-aguntan agbo rẹ̀,tí ó fi Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ̀ sáàrin wọn?

Ka pipe ipin Aisaya 63

Wo Aisaya 63:11 ni o tọ