Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 62:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Jerusalẹmu, mo ti fi àwọn aṣọ́de sí orí odi rẹ;lojoojumọ, tọ̀sán-tòru, wọn kò gbọdọ̀ panumọ́.Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń rán OLUWA létí,ẹ má dákẹ́.

Ka pipe ipin Aisaya 62

Wo Aisaya 62:6 ni o tọ