Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 62:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Sioni, ń kò ní dákẹ́,nítorí Jerusalẹmu, ń kò ní sinmi,títí ìdáláre rẹ̀ yóo fi yọ bí ìmọ́lẹ̀,tí ìgbàlà rẹ̀ yóo sì tàn bí àtùpà.

Ka pipe ipin Aisaya 62

Wo Aisaya 62:1 ni o tọ