Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 60:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹran ọ̀sìn Kedari ni wọ́n óo kó wá fún ọ,wọn óo kó àgbò Nebaiotu wá ta ọ́ lọ́rẹ.Wọn óo jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà lórí pẹpẹ mi,ilé mi lógo, ṣugbọn n óo tún ṣe é lógo sí i.

Ka pipe ipin Aisaya 60

Wo Aisaya 60:7 ni o tọ