Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 60:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí òkùnkùn yóo bo ayé mọ́lẹ̀,òkùnkùn biribiri yóo sì bo àwọn orílẹ̀-èdè mọ́lẹ̀,ṣugbọn ìmọ́lẹ̀ OLUWA yóo tàn sára rẹ,ògo OLUWA yóo sì hàn lára rẹ.

Ka pipe ipin Aisaya 60

Wo Aisaya 60:2 ni o tọ