Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 60:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ti kọ̀ ọ́,wọ́n sì kórìíra rẹ,tí kò sí ẹni tí ń gba ààrin rẹ̀ kọjá mọ́,n óo sọ ọ́ di àmúyangàn títí lae;àní, ohun ayọ̀ láti ìrandíran.

Ka pipe ipin Aisaya 60

Wo Aisaya 60:15 ni o tọ