Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 60:13 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ògo Lẹbanoni yóo wá sí ọ̀dọ̀ rẹ:igi sipirẹsi, igi firi, ati igi pine;láti bukun ẹwà ilé mímọ́ mi,n óo sì ṣe ibi ìtìsẹ̀ mi lógo.

Ka pipe ipin Aisaya 60

Wo Aisaya 60:13 ni o tọ