Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 55:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ tẹ́tí sílẹ̀ kí ẹ súnmọ́ ọ̀dọ̀ mi,ẹ gbọ́ ohun tí mò ń wí kí ẹ lè yè.N óo ba yín dá majẹmu ayérayé,ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ tí mo ṣe ìlérí fún Dafidi.

Ka pipe ipin Aisaya 55

Wo Aisaya 55:3 ni o tọ