Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 55:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí òjò ati yìnyín, tí ń rọ̀ láti ojú ọ̀run,tí wọn kì í pada sibẹ mọ́,ṣugbọn tí wọn ń bomi rin ilẹ̀,tí ń mú kí nǹkan hù jáde;kí àgbẹ̀ lè rí èso gbìn,kí eniyan sì rí oúnjẹ jẹ.

Ka pipe ipin Aisaya 55

Wo Aisaya 55:10 ni o tọ