Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 54:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí àwọn òkè ńlá tilẹ̀ ṣí kúrò,tí a sì ṣí àwọn òkè kéékèèké nídìí,ṣugbọn ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀, kò ní yẹ̀ lára rẹ,majẹmu alaafia mi tí mo bá ọ dá kò ní yẹ̀.Èmi OLUWA tí mo ṣàánú fún ọ ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 54

Wo Aisaya 54:10 ni o tọ