Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 51:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“OLUWA yóo tu Sioni ninu,yóo tu gbogbo àwọn tí ó ṣòfò ninu rẹ̀ ninu;yóo sì sọ aṣálẹ̀ rẹ̀ dàbí Edẹni, ọgbà OLUWA.Ayọ̀ ati ìdùnnú ni yóo máa wà ninu rẹ̀,pẹlu orin ọpẹ́ ati orin ayọ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 51

Wo Aisaya 51:3 ni o tọ