Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 5:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii n óo sọ ohun tí n óo ṣe sí ọgbà àjàrà mi fun yín.N óo tú ọgbà tí mo ṣe yí i ká,iná yóo sì jó o.N óo wó odi tí mo mọ yí i ká,wọn yóo sì tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 5

Wo Aisaya 5:5 ni o tọ