Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 5:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò rẹ ẹnikẹ́ni ninu wọn,ẹnikẹ́ni ninu wọn kò fẹsẹ̀ kọ.Ẹyọ ẹnìkan wọn kò sì sùn,bẹ́ẹ̀ ni wọn kò tòògbé.Àmùrè ẹnìkankan kò tú,bẹ́ẹ̀ ni okùn bàtà ẹnìkankan kò já.

Ka pipe ipin Aisaya 5

Wo Aisaya 5:27 ni o tọ