Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 49:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe ẹnu mi bí idà mímú,ó fi mí pamọ́ sí ibi òjìji ọwọ́ rẹ̀,ó ṣe mí ní ọfà tí ó mú,ó fi mí pamọ́ sinu apó rẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 49

Wo Aisaya 49:2 ni o tọ