Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 48:3 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Láti ìgbà àtijọ́ ni mo ti kéde,àwọn nǹkan tí yóo ṣẹlẹ̀,èmi ni mo sọ wọ́n jáde,tí mo sì fi wọ́n hàn.Lójijì mo ṣe wọ́n,nǹkan tí mo sọ sì ṣẹ.

Ka pipe ipin Aisaya 48

Wo Aisaya 48:3 ni o tọ