Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 48:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ súnmọ́ mi, kí ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí,láti ìbẹ̀rẹ̀ wá, n kò sọ̀rọ̀ ní àṣírí,láti ìgbà tí ọ̀rọ̀ náà ti ṣe ni mo ti wà níbẹ̀.”Nisinsinyii, OLUWA, Ọlọrun, ati Ẹ̀mí rẹ̀ ti rán mi.

Ka pipe ipin Aisaya 48

Wo Aisaya 48:16 ni o tọ