Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 47:5 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí nípa Kalidea pé:“Jókòó kí o dákẹ́ jẹ́ẹ́, kí o sì wọ inú òkùnkùn lọ,ìwọ ọmọbinrin Kalidea.Nítorí a kò ní pè ọ́ ní ayaba àwọn orílẹ̀-èdè mọ́.

Ka pipe ipin Aisaya 47

Wo Aisaya 47:5 ni o tọ