Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 46:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn á gbé e lé èjìká wọn,wọn á gbé e sípò rẹ̀, á sì dúró kabẹ̀.Kò ní le kúrò níbẹ̀ lọ sí ibìkankan.Bí eniyan bá ké pè é, kò lè gbọ́,kò lè yọ eniyan ninu ìṣòro rẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 46

Wo Aisaya 46:7 ni o tọ