Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 46:11-13 BIBELI MIMỌ (BM)

11. Mo pe idì láti ìlà oòrùn,mo sì ti pe ẹni tí yóo mú àbá mi ṣẹ láti ilẹ̀ òkèèrè wá.Mo ti sọ̀rọ̀, n óo sì mú un ṣẹ,mo ti ṣe ìpinnu, n óo sì ṣe é.

12. “Ẹ fetí sí mi, ẹ̀yin aláìgbọràn, ẹ̀yin tí ẹ jìnnà sí ìgbàlà.

13. Mo mú ìdáǹdè mi wá sí tòsí, kò jìnnà mọ́,ìgbàlà mi kò ní pẹ́ dé.N óo fi ìgbàlà mi sí Sioni, fún Israẹli, ògo mi.”

Ka pipe ipin Aisaya 46