Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 45:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ohun tí OLUWA sọ fún kirusi, ẹni tí ó fi àmì òróró yàn nìyí:Ẹni tí OLUWA di ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú, tí ó lò,láti rẹ àwọn orílẹ̀-èdè sílẹ̀ níwájú rẹ̀,láti tú àmùrè àwọn ọba,láti ṣí àwọn ìlẹ̀kùn níwájú rẹ̀,kí ẹnubodè má lè tì.

2. OLUWA ní, “N óo lọ ṣáájú rẹ,n óo sọ àwọn òkè ńlá di pẹ̀tẹ́lẹ̀;n óo fọ́ ìlẹ̀kùn idẹ,n óo sì gé ọ̀pá ìlẹ̀kùn irin.

Ka pipe ipin Aisaya 45