Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 44:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹnìkan yóo wí pé,‘OLUWA ló ni mí.’Ẹnìkejì yóo pe ara rẹ̀ ní orúkọ Jakọbu.Ẹlòmíràn yóo kọ ‘Ti OLUWA ni’ sí apá rẹ̀yóo máa fi orúkọ Israẹli ṣe àpèjá orúkọ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Aisaya 44

Wo Aisaya 44:5 ni o tọ