Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 44:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi tí mo jẹ́rìí sí ọ̀rọ̀ iranṣẹ mi,tí mo sì mú ìmọ̀ àwọn ikọ̀ mi ṣẹ,èmi tí mo wí fún Jerusalẹmu pé,‘Àwọn eniyan yóo máa gbé inú rẹ,’tí mo sì wí fún àwọn ìlú Juda pé,‘A óo tún odi yín mọ,n óo sì tún yín kọ́.’

Ka pipe ipin Aisaya 44

Wo Aisaya 44:26 ni o tọ