Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 44:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbọ́ ohun tí OLUWA, Olùràpadà rẹ wí,ẹni tí ó ṣẹ̀dá rẹ láti inú oyún.Ó ní, “Èmi ni OLUWA, tí mo dá ohun gbogbo.Èmi nìkan ni mo tẹ́ ojú ọ̀run,tí mo sì dá ilẹ̀ ayé tẹ́,

Ka pipe ipin Aisaya 44

Wo Aisaya 44:24 ni o tọ