Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 44:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà igi yìí di igi ìdáná: Eniyan óo gé ninu rẹ̀, yóo fi dáná yá; yóo gé ninu rẹ̀ yóo fi dáná oúnjẹ; yóo gé ninu rẹ̀, yóo fi gbẹ́ ère, yóo máa bọ ọ́. Eniyan á wá sọ igi lásán tí ó gbẹ́ di oriṣa, á sì máa foríbalẹ̀ fún un.

Ka pipe ipin Aisaya 44

Wo Aisaya 44:15 ni o tọ